Ise isenbaye
Download
1 / 10

ISE ISENBAYE - PowerPoint PPT Presentation


 • 2718 Views
 • Uploaded on

ISE ISENBAYE. ISE AGBE ATI ISE ILU LILU. ORIKI ISE ISENBAYE. Ise isenbaye naa ni a mo si ISE ABINIBI. O je ise ti a jogun lati owo awon baba nla wa. APEERE ISE ISENBAYE Owo sise Ona sise Ope kiko Ise ila kiko Ise agbe , Ise ode, Ise ilu lilu , Ise agbede ,

loader
I am the owner, or an agent authorized to act on behalf of the owner, of the copyrighted work described.
capcha
Download Presentation

PowerPoint Slideshow about ' ISE ISENBAYE' - jordan-david


An Image/Link below is provided (as is) to download presentation

Download Policy: Content on the Website is provided to you AS IS for your information and personal use and may not be sold / licensed / shared on other websites without getting consent from its author.While downloading, if for some reason you are not able to download a presentation, the publisher may have deleted the file from their server.


- - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - E N D - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - - -
Presentation Transcript
Ise isenbaye

ISE ISENBAYE

ISE AGBE ATI ISE ILU LILU


Oriki ise isenbaye
ORIKI ISE ISENBAYE

 • Iseisenbayenaani a mo si ISE ABINIBI.

 • O je iseti a jogunlatiowoawonbabanlawa

 • APEERE ISE ISENBAYE

 • OwosiseOnasiseOpekikoIseilakiko

 • Iseagbe , Ise ode, Iseilulilu, Iseagbede,

 • Isearodida, Iseirundidi


Ise agbe

 • .

 • AGBE AYE ATIJO

 • ORISIIRISII AGBE AYE ATIJO

 • AGBE ALAROJE– o n daokokekere fun ohunjejije.

 • Apeere ere oko re : ogede, agbado, isu. ege, eree, ataatiewebe.

 • AGBE OLOKO NLA- o n daokonlalatigbinohunjijeatiigiowobiikoko, ope, kofi, obi, orogbo, atiigiroba.

 • Won maa n lo eruatiiwofafun iseloko.

 • Awoniyawo, omoatiebinaamaa n ran won lowo.

ISE AGBE

 • Iseagbe je iseokoriro, ohunogbingbingbinatieranosinsinsin


Ise agbe ode oni
ISE AGBE ODE - ONI

 • Awonagbe ode- oniniawonti o n lo awoneroigbalodelatisiseagbe

 • ORISIIRISII AGBE ODE – ONI.

 • Agbealaroje –won daokoohunjijelatipese fun ebi won.

 • Agbeolokonla –awonwonyii n daokolatifisise se.

 • Agbeolohunosin – awonti o n sin erankobiiMaluu. AdiyeatiElede.


Ohun elo ise agbe
OHUN ELO ISE AGBE

 • OHUN ELO ISE AGBE AYE ATIJO

Oko, Ada , Akoro, Aake, atiObe

.

 • OHUN ELO ISE AGBE ODE-ONI

 • OogunajileEroigbalode – Katakata,eroiroleatiikobe.

 • Irugbintikiipe so.

 • Oogunajile.


Orisiirisii oko
ORISIIRISII OKO

 • OKO EGAN – Ile aginjuti a seseda. Ile oloraa o dara fun gbingbinIgiowobiikokoorogbo, obi, robaatiope.

 • OKO ODAN – Ile pupa, o dara fun gbingbinohunjebiiagbado, ege, isu, eree, okaa-baba,owu, anamo. Egunsi, ata, ilaatiewebe.

 • OKO ODO/AKURO – Ile olomi. Okoebaodoni, o dara fun gbingbinagbado, ogede, ata,ilaatiewebebiiefoatiewedu.


Itoju ire oko
ITOJU IRE OKO

 • Ni aye atijoinuabatabi aka ni won maa n toju ire okosi.

 • NI aye ode-onioogunni won maa n fisi ire okoki o ma baa nikokoro.

 • PATAKI ISE AGBE

 • Ipeseohunjije fun awujo.

 • Ipeseise fun awoneniyan.

 • Ipeseohunelo fun awonile-isegbogbo.

 • Ipawowolesiapoijoba, paapaaloriawonohunti a bafisowosiokeokun.


Ilu lilu
ILU LILU

 • Iran Ayanatiomoti won torolowoAyangalu lo n lulu.

 • Oruko to awononilumaa n je niAyanbunmi, Ayanleke, Ayandele, Alayanande, Ayangbemi , abblo.

 • Iseamuluudunniiseilulilu.

  DIE NINU ORISIIRISII ILU TI O WA NILE YORUBA.

 • Dundun, Gangan, Adamo, Ibembe, Igbin, Agere, IpeseOsugbo, Agogo, Apepe, Sanba, Sakara, Agidigbo, Aran

  atiKiriboto.


Ohun elo ilu
OHUN ELO ILU

 • Igi, awo, atiosan

 • PATAKI ILU LILU

 • Fun ayeye – b.aisomoloruko, isinkuagba, igbeyawo, isile. Atiiwuye

 • Fun ijosin – b.abata fun sango.

 • Fun ipolowooja.

 • Fun kikioba.

 • Fun ogun - imoriyaatiitani-lolobo.

 • Fun ikede.


Ise sise
ISE SISE

 • 1.Dahun ibeereti o wanioju ewe 105 (pg 105) iwe Simplified Yoruba L1 For J.S 1. latiowoAdewoyin S.Y.

 • 2. Yaorisiiilumarun-un ti o bawu o.


ad